Ìṣe Àwọn Aposteli 5:28 BIBELI MIMỌ (BM)

“Mo ṣebí a pàṣẹ fun yín pé kí ẹ má fi orúkọ yìí kọ́ ẹnikẹ́ni mọ́? Sibẹ gbogbo ará Jerusalẹmu ni ó ti gbọ́ nípa ẹ̀kọ́ yín yìí. Ẹ wá tún di ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ ọkunrin yìí lé wa lórí?”

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:25-38