Ìṣe Àwọn Aposteli 5:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin yìí yọ sílẹ̀ ninu owó tí wọ́n rí lórí rẹ̀, ó bá mú ìyókù wá siwaju àwọn aposteli. Iyawo rẹ̀ sì mọ̀ nípa rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:1-3