Ìṣe Àwọn Aposteli 5:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di òru, angẹli Oluwa ṣí ìlẹ̀kùn ilé-ẹ̀wọ̀n, ó sìn wọ́n jáde, ó sọ fún wọn pé,

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:9-20