Ìṣe Àwọn Aposteli 4:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ọjọ́ keji, àwọn ìjòyè ati àwọn àgbààgbà ati àwọn amòfin péjọ ní Jerusalẹmu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:1-15