Ìṣe Àwọn Aposteli 4:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí òdodo ni pé Hẹrọdu ati Pọntiu Pilatu pẹlu àwọn tí kì í ṣe Juu ati àwọn eniyan Israẹli péjọpọ̀ ní ìlú yìí, wọ́n ṣe ohun tí ó lòdì sí ọmọ mímọ́ rẹ, Jesu tí o ti fi òróró yàn ní Mesaya,

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:23-30