Ìṣe Àwọn Aposteli 4:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n gbọ́, wọ́n jọ ké pe Ọlọrun pé, “Oluwa, ìwọ tí ó dá ọ̀run ati ayé ati òkun ati gbogbo ohun tí ó wà ninu wọn,

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:20-25