Ìṣe Àwọn Aposteli 4:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí wọ́n tún halẹ̀ mọ́ wọn, wọ́n dá wọn sílẹ̀, nítorí wọn kò rí ọ̀nà tí wọn ìbá fi jẹ wọ́n níyà, nítorí àwọn eniyan. Gbogbo eniyan ni wọ́n sì ń fi ìyìn fún Ọlọrun fún ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:15-24