Ìṣe Àwọn Aposteli 4:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú bí wọn nítorí wọ́n ń kọ́ àwọn eniyan pé àwọn òkú yóo jí dìde. Wọ́n fi ajinde ti Jesu ṣe àpẹẹrẹ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:1-4