Ìṣe Àwọn Aposteli 4:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Peteru ati Johanu dá wọn lóhùn pé, “Èwo ni ó tọ́ níwájú Ọlọrun: kí á gbọ́ràn si yín lẹ́nu ni, tabi kí á gbọ́ràn sí Ọlọrun lẹ́nu? Ẹ̀yin náà ẹ dà á rò.

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:13-28