Ìṣe Àwọn Aposteli 3:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Ọlọrun gbé Ọmọ rẹ̀ dìde, ẹ̀yin ni ó kọ́kọ́ rán an sí, kí ó lè bukun yín láti mú kí ẹnìkọ̀ọ̀kan yín yipada kúrò ní ọ̀nà burúkú rẹ̀.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 3

Ìṣe Àwọn Aposteli 3:17-26