Ìṣe Àwọn Aposteli 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan wà tí wọn máa ń gbé wá sibẹ, tí ó yarọ láti inú ìyá rẹ̀ wá. Lojoojumọ, wọn á máa gbé e wá sí ẹnu ọ̀nà Tẹmpili tí à ń pè ní “Ẹnu Ọ̀nà Dáradára,” kí ó lè máa ṣagbe lọ́dọ̀ àwọn tí ń wọ inú Tẹmpili lọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 3

Ìṣe Àwọn Aposteli 3:1-8