Ìṣe Àwọn Aposteli 3:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni Ọlọrun ṣe mú ohun tí ó ti sọ tẹ́lẹ̀ láti ẹnu gbogbo àwọn wolii rẹ̀ ṣẹ, pé Mesaya òun níláti jìyà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 3

Ìṣe Àwọn Aposteli 3:16-20