Ìṣe Àwọn Aposteli 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun Abrahamu, Ọlọrun Isaaki ati Ọlọrun Jakọbu, Ọlọrun àwọn baba wa ni ó dá Ọmọ rẹ̀, Jesu lọ́lá. Jesu yìí ni ẹ fi lé àwọn ọ̀tá lọ́wọ́, òun ni ẹ sẹ́ níwájú Pilatu nígbà tí ó fi dá a sílẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 3

Ìṣe Àwọn Aposteli 3:10-22