Ìṣe Àwọn Aposteli 3:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ṣe akiyesi pé ẹni tí ó ti máa ń jókòó ṣagbe lẹ́nu Ọ̀nà Dáradára Tẹmpili ni. Ẹnu yà wọ́n, wọ́n ta gìrì sí ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí ọkunrin náà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 3

Ìṣe Àwọn Aposteli 3:7-19