Ìṣe Àwọn Aposteli 28:22 BIBELI MIMỌ (BM)

A rò pé ó dára kí á gbọ́ ohun tí o ní lọ́kàn, nítorí pé ó ti dé etígbọ̀ọ́ wa pé níbi gbogbo ni àwọn eniyan lòdì sí ẹgbẹ́ tí ó yàtọ̀ yìí.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:15-31