Ìṣe Àwọn Aposteli 28:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí nìyí tí mo fi ranṣẹ pè yín láti ri yín kí n sì ba yín sọ̀rọ̀; nítorí ohun tí Israẹli ń retí ni wọ́n ṣe fi ẹ̀wọ̀n so mí báyìí.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:19-29