Ìṣe Àwọn Aposteli 28:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n wádìí ọ̀rọ̀ lẹ́nu mi, wọ́n fẹ́ dá mi sílẹ̀ nítorí wọn kò rí ohunkohun tí mo ṣe tí wọ́n fi lè dá mi lẹ́bi ikú.

Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:11-24