Ìṣe Àwọn Aposteli 28:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí a wọ Romu, wọ́n gba Paulu láàyè láti wá ilé gbé pẹlu ọmọ-ogun kan tí wọ́n fi ṣọ́ ọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:15-22