Ìṣe Àwọn Aposteli 28:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n yẹ́ wa sí pupọ. Nígbà tí a óo sì fi ṣíkọ̀, wọ́n fún wa ní àwọn nǹkan tí a lè nílò lọ́nà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:6-14