Ìṣe Àwọn Aposteli 27:9 BIBELI MIMỌ (BM)

A pẹ́ níbẹ̀. Ewu ni bí a bá fẹ́ máa bá ìrìn àjò wa lọ nítorí ọjọ́ ààwẹ̀ ti kọjá. Paulu bá gbà wọ́n níyànjú;

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:8-13