Ìṣe Àwọn Aposteli 27:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Níbẹ̀ ni balogun ọ̀rún tí ó ń mú wa lọ ti rí ọkọ̀ Alẹkisandria kan tí ó ń lọ sí Itali. Ni a bá wọ̀ ọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:2-8