Ìṣe Àwọn Aposteli 27:44 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí àwọn yòókù wá tẹ̀lé wọn, kí wọ́n dì mọ́ pákó tabi kí wọ́n dì mọ́ ara ọkọ̀ tí ó ti fọ́. Báyìí ni gbogbo wa ṣe gúnlẹ̀ ní alaafia.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:42-44