Ìṣe Àwọn Aposteli 27:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ọkọ̀ rọ́lu ilẹ̀ níbi tí òkun kò jìn, ni ó bá dúró gbọnin. Iwájú ọkọ̀ wọ inú iyanrìn, kò ṣe é yí. Ẹ̀yìn ọkọ̀ kò kanlẹ̀, ìgbì wá bẹ̀rẹ̀ sí fọ́ ọ bí ó ti ń bì lù ú.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:38-44