Ìṣe Àwọn Aposteli 27:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti ibẹ̀, a ṣíkọ̀, nítorí pé afẹ́fẹ́ ṣọwọ́ òdì sí wa, a gba apá Kipru níbi tí afẹ́fẹ́ kò ti fẹ́ pupọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:1-6