Ìṣe Àwọn Aposteli 27:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà ẹ̀yin eniyan, ẹ ṣara gírí, nítorí mo gba Ọlọrun gbọ́ pé bí ó ti sọ fún mi ni yóo rí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:15-35