Ìṣe Àwọn Aposteli 27:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ó ti rí yìí náà, mo gbà yín níyànjú pé kí ẹ ṣara gírí. Ẹ̀mí ẹnikẹ́ni ninu yín kò ní ṣòfò; ọkọ̀ nìkan ni yóo ṣòfò.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:20-32