Ìṣe Àwọn Aposteli 26:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìrètí yìí ni àwọn ẹ̀yà mejila tí ó wà ní orílẹ̀-èdè wa ní, tí wọ́n ṣe ń fi ìtara sin Ọlọrun tọ̀sán-tòru. Nítorí ohun tí à ń retí yìí ni àwọn Juu fi ń rojọ́ mi, Kabiyesi!

Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Ìṣe Àwọn Aposteli 26:3-10