Ìṣe Àwọn Aposteli 26:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bọ́ sápá kan, wọ́n ń sọ fún wọn pé, “Ọkunrin yìí kò ṣe ohunkohun tí ó fi jẹ̀bi ikú tabi ẹ̀wọ̀n.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Ìṣe Àwọn Aposteli 26:26-32