Ìṣe Àwọn Aposteli 26:3 BIBELI MIMỌ (BM)

pàápàá nítorí ẹ mọ gbogbo àṣà àwọn Juu dáradára, ẹ sì mọ àríyànjiyàn tí ó wà láàrin wọn. Nítorí náà mo bẹ̀ yín kí ẹ fi sùúrù gbọ́ ọ̀rọ̀ mi.

Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Ìṣe Àwọn Aposteli 26:2-13