Ìṣe Àwọn Aposteli 26:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Paulu ti ń sọ̀rọ̀ báyìí, Fẹstu ké mọ́ ọn pé, “Paulu, orí rẹ dàrú! Ìwé àmọ̀jù ti dà ọ́ lórí rú.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Ìṣe Àwọn Aposteli 26:16-32