Ìṣe Àwọn Aposteli 25:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé Fẹstu ń wá ojurere àwọn Juu, ó bi Paulu pé, “Ṣé o óo kálọ sí Jerusalẹmu, kí n dá ẹjọ́ yìí níbẹ̀?”

Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Ìṣe Àwọn Aposteli 25:8-10