Ìṣe Àwọn Aposteli 25:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ọjọ́ keji, Agiripa ati Berenike bá dé pẹlu ayẹyẹ. Wọ́n wọ gbọ̀ngàn ní ààfin pẹlu àwọn ọ̀gágun ati àwọn eniyan jàǹkànjàǹkàn ní ìlú. Fẹstu bá pàṣẹ kí wọ́n mú Paulu wá.

Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Ìṣe Àwọn Aposteli 25:17-27