Ìṣe Àwọn Aposteli 25:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Paulu ní kí á fi òun sílẹ̀ ní ìtìmọ́lé títí Kesari yóo fi lè gbọ́ ẹjọ́ òun. Mo bá pàṣẹ kí wọ́n fi í sílẹ̀ ní ìtìmọ́lé títí tí n óo fi lè fi ranṣẹ sí Kesari.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Ìṣe Àwọn Aposteli 25:14-23