Ìṣe Àwọn Aposteli 25:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn tí ó fi ẹ̀sùn kàn án dìde láti sọ̀rọ̀, wọn kò mẹ́nuba irú àwọn ọ̀ràn tí mo rò pé wọn yóo sọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Ìṣe Àwọn Aposteli 25:13-27