Ìṣe Àwọn Aposteli 25:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Fẹstu forí-korí pẹlu àwọn olùbádámọ̀ràn rẹ̀, ó wá dáhùn pé, “O ti gbé ẹjọ́ rẹ lọ siwaju ọba Kesari; nítorí náà o gbọdọ̀ lọ sọ́dọ̀ ọba Kesari.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Ìṣe Àwọn Aposteli 25:3-17