Ìṣe Àwọn Aposteli 25:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn ọjọ́ mẹta tí Fẹstu dé sí agbègbè ibi iṣẹ́ rẹ̀, ó lọ sí Jerusalẹmu láti Kesaria.

Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Ìṣe Àwọn Aposteli 25:1-10