Ìṣe Àwọn Aposteli 24:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun ni ó pàṣẹ pé kí àwọn tí wọ́n fi ẹ̀sùn kàn án wá siwaju yín.] Bí ẹ bá wádìí lẹ́nu òun fúnrarẹ̀, ẹ óo rí i pé òtítọ́ ni gbogbo ẹjọ́ rẹ̀ tí a fi sùn yín.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 24

Ìṣe Àwọn Aposteli 24:3-11