Ìṣe Àwọn Aposteli 23:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó sọ báyìí, ìyapa bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn Farisi ati àwọn Sadusi, ìgbìmọ̀ bá pín sí meji.

Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:1-11