Ìṣe Àwọn Aposteli 23:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Gomina ka ìwé náà. Ó wá wádìí pé apá ibo ni Paulu ti wá. Wọ́n sọ fún un pé ní agbègbè Silisia ni.

Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:24-35