Ìṣe Àwọn Aposteli 23:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Paulu wá sọ fún un pé, “Ọlọrun yóo lù ọ́. Ìwọ ògiri tí wọ́n kùn lẹ́fun lásán yìí! O jókòó sibẹ, ò ń dá mi lẹ́jọ́ lórí Òfin, sibẹ o pa Òfin tì, o ní kí wọ́n lù mí.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:1-9