Ìṣe Àwọn Aposteli 23:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Juu mú ọkunrin yìí, wọ́n fẹ́ pa á. Mo gbà á lọ́wọ́ wọn pẹlu àwọn ọmọ-ogun mi nítorí mo gbọ́ pé ọmọ-ìbílẹ̀ Romu ni.

Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:20-35