Ìṣe Àwọn Aposteli 23:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n lọ sọ́dọ̀ àwọn olórí alufaa ati àwọn àgbààgbà, wọ́n ní, “A ti jẹ́jẹ̀ẹ́, a sì ti búra pé a kò ní fẹnu kan nǹkankan títí a óo fi pa Paulu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:6-23