Ìṣe Àwọn Aposteli 23:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, àwọn Juu péjọ pọ̀ láti dìtẹ̀ sí Paulu. Wọ́n búra pé àwọn kò ní jẹun, bẹ́ẹ̀ ni àwọn kò ní mu omi títí àwọn yóo fi pa Paulu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:10-16