Ìṣe Àwọn Aposteli 22:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Olórí Alufaa pàápàá lè jẹ́rìí mi, ati gbogbo àwọn àgbààgbà. Ọwọ́ wọn ni mo ti gba ìwé lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn arakunrin wa ní Damasku. Mo lọ sibẹ láti de àwọn ẹlẹ́sìn yìí kí n sì mú wọn wá sí Jerusalẹmu láti jẹ wọ́n níyà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Ìṣe Àwọn Aposteli 22:2-12