Ìṣe Àwọn Aposteli 22:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n mọ̀ pé nígbà tí wọ́n pa Stefanu, ẹlẹ́rìí rẹ, bí mo ti dúró nìyí, tí mò ń kan sáárá sí àwọn tí ó pa á tí mò ń ṣọ́ aṣọ wọn.’

Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Ìṣe Àwọn Aposteli 22:18-25