Ìṣe Àwọn Aposteli 21:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìyẹn ni pé kì í ṣe ìwọ ni ará Ijipti tí ó dá rúkèrúdò sílẹ̀ láìpẹ́ yìí, tí ó kó ẹgbaaji (4000) àwọn agúnbẹ lẹ́yìn lọ sí aṣálẹ̀?”

Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Ìṣe Àwọn Aposteli 21:36-40