Ìṣe Àwọn Aposteli 21:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sọ báyìí nítorí pé wọ́n ti kọ́kọ́ rí Tirofimọsi ará Efesu pẹlu Paulu láàrin ìlú, wọ́n wá ṣebí Paulu mú un wọ inú Tẹmpili ni.

Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Ìṣe Àwọn Aposteli 21:21-38