Ìṣe Àwọn Aposteli 20:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọdọmọkunrin kan tí ó ń jẹ́ Yutiku jókòó lórí fèrèsé. Ó ti sùn lọ níbi tí Paulu gbé ń sọ̀rọ̀ lọ títí. Nígbà tí oorun wọ̀ ọ́ lára, ó ré bọ́ sílẹ̀ láti orí pẹ̀tẹ́ẹ̀sì kẹta. Nígbà tí wọn óo gbé e, ó ti kú.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:1-10