Ìṣe Àwọn Aposteli 20:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn bá ń sunkún. Wọ́n ń dì mọ́ ọn, wọ́n ń fi ẹnu kò ó lẹ́nu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:33-38