Ìṣe Àwọn Aposteli 20:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ṣọ́ra yín, ẹ sì ṣọ́ agbo tí Ẹ̀mí Mímọ́ fi yín ṣe alabojuto lórí rẹ̀, kí ẹ máa bọ́ ìjọ Ọlọrun tí ó fi ẹ̀jẹ̀ Ọmọ rẹ̀ ṣe ní tirẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:23-34